Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shallum: 9. Father of Jehizkiah
Àwọn ẹsẹ nípa 9. Father of Jehizkiah
Lẹ́yìn náà, díẹ̀ nínú àwọn olórí ní Efraimu, Asariah ọmọ Jehohanani, Berekiah ọmọ Meṣilemoti, Jehiskiah ọmọ Ṣallumu, àti Amasa ọmọ Hadlai, dìde sí àwọn tí o ti ogun náà bọ̀.