Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Regency
Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì
Nígbà náà kò sí ọba ní Edomu; adelé kan ni ọba.
Olúwa sì kọlu ọba náà pẹ̀lú ẹ̀tẹ̀, títí di ọjọ́ tí ó kú, ó sì ń gbé ní ilé ọ̀tọ̀. Jotamu, ọmọ ọba sì tọ́jú ààfin, ó sì ń darí àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà.