Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Perfume: Used in the tabernacle
Àwọn ẹsẹ nípa Used in the tabernacle
“Aaroni yóò sì máa jó tùràrí dídùn lórí pẹpẹ náà ní àràárọ̀, nígbà tí ó tún àwọn fìtílà náà ṣe.
Wọ́n sì tún mú olóòórùn àti òróró olifi wá fún títanná àti fún òróró ìtasórí àti fún tùràrí dídùn.