Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Paseah: 3. Father of Jehoiada, probably identical with preceding
Àwọn ẹsẹ nípa 3. Father of Jehoiada, probably identical with preceding
Jehoida ọmọ Pasea àti Meṣullamu ọmọ Besodeiah ni wọ́n tún ẹnu ibodè àtijọ́ ṣe. Wọ́n kún bíìmù rẹ̀, wọ́n ri àwọn ìlẹ̀kùn rẹ̀, àwọn ìdábùú ìlẹ̀kùn àti àwọn ìdè rẹ̀ sí ààyè wọn.