Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nicolas: A proselyte of Antioch, and deacon of the church at Jerusalem.

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa A proselyte of Antioch, and deacon of the church at Jerusalem.

  1. Ọ̀rọ̀ náà sì tọ́ lójú gbogbo ìjọ; wọ́n sì yan Stefanu, ọkùnrin tí ó kún fún ìgbàgbọ́ àti fún Ẹ̀mí Mímọ́ àti Filipi, àti Prokoru, àti Nikanoru, àti Timoni, àti Parimena, àti Nikolasi aláwọ̀ṣe Júù ará Antioku.

  2. Ẹni tí wọ́n mú dúró níwájú àwọn Aposteli; nígbà tí wọ́n sì gbàdúrà, wọ́n gbé ọwọ́ lé wọn.