Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Natural Death: Levels all ranks

3 ẹsẹ · 32 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Levels all ranks

  1. Níbẹ̀ ni ẹni búburú ṣíwọ́ ìyọnilẹ́nu, níbẹ̀ ni ẹni àárẹ̀ wà nínú ìsinmi.

  2. Níbẹ̀ ni àwọn ìgbèkùn sinmi pọ̀, wọn kò gbóhùn amúnisìn mọ́.

  3. Àti èwe àti àgbà wà níbẹ̀, ẹrú sì di òmìnira kúrò lọ́wọ́ olówó rẹ̀.