Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mob: At Thessalonica

1 ẹsẹ · 3 abala

Àwọn ẹsẹ nípa At Thessalonica

  1. Ṣùgbọ́n àwọn Júù jowú, wọn sì fa àwọn jàgídíjàgan nínú àwọn ọmọ ènìyàn mọ́ra, wọ́n ko ẹgbẹ́ jọ, wọ́n sì ń dá ìlú rú; wọ́n sì kọlu ilé Jasoni, wọ́n ń fẹ́ láti mú Paulu àti Sila jáde tọ àwọn ènìyàn lọ.