Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Meshullemeth: Wife of Manasseh and mother of Amon.
Àwọn ẹsẹ nípa Wife of Manasseh and mother of Amon.
Amoni jẹ́ ẹni ọdún méjìlélógún nígbà tí ó jẹ ọba. Orúkọ màmá rẹ̀ a sì máa jẹ́ Meṣulemeti ọmọbìnrin Harusi: ó wá láti Jotba, ó sì jẹ ọba ní Jerusalẹmu fún ọdún méjì.