Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Meholathite: An inhabitant of a city in Issachar.

2 ẹsẹ · 1 abala

Àwọn ẹsẹ nípa An inhabitant of a city in Issachar.

  1. Nígbà tí àkókò tó fún Merabu, ọmọbìnrin Saulu, láti fi fún Dafidi, ni a sì fi fún Adrieli ará Mehola ní aya.

  2. Ọba sì mú àwọn ọmọkùnrin méjèèjì tí Rispa ọmọbìnrin Aiah bí fún Saulu, àní Ammoni àti Mefiboṣeti àwọn ọmọkùnrin márààrún ti Merabu, ọmọbìnrin Saulu, àwọn tí ó bí fún Adrieli ọmọ Barsillai ará Mehola.