Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mattithiah: 3. A chief of the fourteenth division of temple musicians

2 ẹsẹ · 5 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 3. A chief of the fourteenth division of temple musicians

  1. Gẹ́gẹ́ bí ti Jedutuni, nínú àwọn ọmọkùnrin rẹ̀: Gedaliah, Seri, Jeṣaiah, Ṣimei, Haṣabiah àti Mattitiah, mẹ́fà nínú gbogbo wọn, lábẹ́ ìbojútó baba wọn Jedutuni, ẹni tí ó sọtẹ́lẹ̀, ẹni tí ó lo dùùrù láti dúpẹ́ àti láti yin Olúwa.

  2. ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnlá sí Mattitiah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá