Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Heedfulness: Commanded 3 ẹsẹ · 17 abala Wá "Heedfulness" Gbogbo 3 Commanded 3 Against false Christs, and false prophets · Against false teachers · Against idolatry · Against presumption · Against sin · Against unbelief · In conduct · In giving judgment · In how we hear · In keeping God's commandments · In speech · In the care of the soul · In the house and worship of God · In what we hear · In worldly company · Promises to · Fi gbogbo 18 hàn Àwọn ẹsẹ nípa Commanded Òwe 4:25Jẹ́ kí ojú rẹ máa wo iwájú, jẹ́ kí ìwo ojú rẹ máa wo ọ̀kánkán iwájú rẹ sá á.Òwe 4:26Kíyèsi ìrìn ẹsẹ̀ rẹ sì rìn ní àwọn ọ̀nà tí ó dára nìkan.Òwe 4:27Má ṣe yà sọ́tùn ún tàbí sósì; pa ẹsẹ̀ rẹ mọ́ kúrò nínú ibi.