Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Decrees: Ecclesiastical, of the church at Jerusalem

2 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Ecclesiastical, of the church at Jerusalem

  1. Nítorí ó dára lójú Ẹ̀mí Mímọ́, àti lójú wa, kí a má ṣe di ẹrù le é yin lórí, bí kò ṣe àwọn nǹkan wọ̀nyí tí ó ṣe pàtàkì;

  2. í ẹ̀yin fàsẹ́yìn kúrò nínú ẹran ti à pa bọ òrìṣà, àti nínú ẹ̀jẹ̀ àti nínú ohun ìlọ́lọ́rùnpa, àti nínú àgbèrè. Bí ẹ̀yin bá pa ara yín mọ́ kúrò, ẹ̀yin ó ṣe rere. Àlàáfíà.