Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Chancellor 2 ẹsẹ · 1 abala Wá "Chancellor" Gbogbo 2 A state officer. 2 Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì Esra 4:8Rehumu balógun àti Ṣimṣai akọ̀wé jùmọ̀ kọ́ ìwé láti dojúkọ Jerusalẹmu sí Artasasta ọba báyìí:Esra 4:9Rehumu balógun àti Ṣimṣai akọ̀wé, pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn tókù—àwọn ará Dina, ti Afarsatki, ti Tarpeli, ti Afarsi, Ereki àti Babeli, àwọn ará Elamu ti Susa,