Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Breastplate: Had names of the tribes engraved on precious stones

5 ẹsẹ · 16 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Had names of the tribes engraved on precious stones

  1. Nígbà náà ni ìwọ yóò de òkúta oníyebíye mẹ́rin sára ẹsẹ̀ rẹ̀. Ní ẹsẹ̀ àkọ́kọ́ ni kí rúbì, topasi àti berili wà;

  2. ní ẹsẹ̀ kejì turikuose, emeradi, safire, àti diamọndi;

  3. ní ẹsẹ̀ kẹta, jasiniti, agate, àti ametisiti;

  4. ní ẹsẹ̀ kẹrin, topasi, àti óníkìsì àti jasperi. A ó sì tò wọ́n sí ojú wúrà ní dìde wọn.

  5. Òkúta méjìlá yóò wà, ọ̀kọ̀ọ̀kan fún orúkọ àwọn ọmọ Israẹli olúkúlùkù èdìdì àmì pẹ̀lú orúkọ ẹnìkọ̀ọ̀kan bí ẹ̀yà Israẹli méjìlá.