Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Ax: Elisha causes to swim 2 ẹsẹ · 4 abala Wá "Ax" Gbogbo 6 An implement 4 Elisha causes to swim 2 Battle ax · Figurative · Àwọn ẹsẹ nípa Elisha causes to swim 2 Ọba 6:5Bí ọ̀kan ṣe gé igi náà, àáké irin náà bọ́ sínú omi, ó kígbe sókè pé, “O! Olúwa mi, mo yá a ni!”2 Ọba 6:6Ènìyàn Ọlọ́run sì béèrè pé, “Níbo ni ó bọ́ sí?” Nígbà tí ó fi ibẹ̀ hàn án, Eliṣa gé igi kan ó sì jù ú síbẹ̀, ó sì mú irin náà fò lójú omi.