Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Advocate: Figurative

1 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Figurative

  1. Ẹ̀yin ọmọ mi ọ̀wọ́n, mo kọ ìwé nǹkan wọ̀nyí sí yín, kí ẹ̀yin má bà á dẹ́ṣẹ̀. Ṣùgbọ́n bí ẹnikẹ́ni bá sì dẹ́ṣẹ̀, àwa ni alágbàwí lọ́dọ̀ Baba: Jesu Kristi, olódodo nìkan.