Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Adrammelech: 1. An Assyrian idol

1 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 1. An Assyrian idol

  1. àti àwọn ará Afa ṣe Nibhasi àti Tartaki, àti àwọn ará Sefarfaimi sun àwọn ọmọ wọn níná gẹ́gẹ́ bí ẹbọ sí Adrameleki àti Anameleki, àwọn òrìṣà Sefarfaimi.