Tiphsah
35.8400, 38.7300 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Tiphsah
Nítorí òun ni ó ṣàkóso lórí gbogbo agbègbè ní ìhà ìwọ̀-oòrùn odò Eufurate, láti Tifisa títí dé Gasa, lórí gbogbo àwọn ọba ní ìhà ìhín odò, ó sì ní àlàáfíà ní gbogbo ìlú tí ó yí i káàkiri.