Syrtis
A tún mọ̀ ọ́n sí: quicksands
31.7600, 18.5000 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Syrtis
Nígbà tí wọ́n sì gbé e sókè, wọn sa agbára láti dí ọkọ̀-òkun náà nísàlẹ̀, nítorí tí wọ́n ń bẹ̀rù kí á máa ba à gbé wọn sórí iyanrìn dídẹ̀, wọn fi ìgbokùn sílẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni a sì ń gbá wa kiri.