Skip to content

Pirathon

4 verses · 2 known names

A tún mọ̀ ọ́n sí: Pirathonite

32.2800, 35.0200 Wo lórí Google Maps

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Pirathon

  1. Abdoni ọmọ Hileli sì kú, wọ́n sin ín sí Piratoni ní ilé Efraimu ní ìlú òkè àwọn ará Amaleki.

  2. Benaiah ará Piratoni, Hiddai ti àfonífojì Gaaṣi,

  3. Itai ọmọ Ribai láti Gibeah ní Benjamini, Benaiah ará Piratoni,

  4. Ìkọkànlá fún oṣù kọkànlá jẹ́ Benaiah ará Piratoni ará Efraimu ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín tirẹ̀.