Paddan
A tún mọ̀ ọ́n sí: Padan
36.8600, 39.0300 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Paddan
Bí mo ti ń padà láti Padani, Rakeli kú ní ọ̀nà nígbà tí ó ṣì wà ní ilẹ̀ Kenaani, èyí tó mú ìbànújẹ́ bá mi, níbi tí kò jìnnà sí Efrata. Nítorí náà èmí sì sin ín sí ẹ̀bá ọ̀nà tí ó lọ sí Efrata” (tí ṣe Bẹtilẹhẹmu).