Skip to content

Anab

2 verses

31.4000, 34.9400 Wo lórí Google Maps

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Anab

  1. Ní àkókò náà ni Joṣua lọ tí ó sì run àwọn ará Anaki kúrò ní ilẹ̀ òkè, láti Hebroni, Debiri, àti ní Anabu, àti gbogbo ilẹ̀ Juda, àti kúrò ní gbogbo ilẹ̀ òkè Israẹli. Joṣua sì run gbogbo wọn pátápátá àti ìlú wọn.

  2. Anabu, Eṣitemo, Animu,