Adriatic Sea
A tún mọ̀ ọ́n sí: Adria
42.4100, 16.3700 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Adriatic Sea
Ṣùgbọ́n nígbà tí ó di òru ọjọ́ kẹrìnlá, bí a ti ń gbé wa kọjá lọ láàrín Òkun Adria, láàrín ọ̀gànjọ́ àwọn atukọ̀ funra pé, àwọn súnmọ́ etí ilẹ̀ kan.