Addar
A tún mọ̀ ọ́n sí: Adar
30.9500, 34.7100 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Addar
ó sì gba gúúsù Akrabbimu lọ, títí dé Sini àti sí iwájú ìhà gúúsù Kadeṣi-Barnea. Nígbà náà ó sì tún kọjá Hesroni lọ sí Adari, ó sì tún yípo yíká lọ sí Karka.