Shubael
A tún mọ̀ ọ́n sí: Shebuel
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Shubael
Àwọn ọmọ Gerṣomu: Ṣubaeli sì ni alákọ́kọ́.
Ìyókù àwọn ọmọ Lefi. Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Amramu: Ṣubaeli láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ṣubaeli; Jehdeiah.
Ṣubaeli, ìran ọmọ Gerṣomu ọmọ Mose jẹ́ olórí tí ó bojútó ilé ìṣúra.