Skip to content

Shearjashub

1 ẹsẹ · 2 ọmọ ẹbí

A tún mọ̀ ọ́n sí: Shear-jashub

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Shearjashub

  1. Lẹ́yìn èyí, Olúwa sọ fún Isaiah pé, “Jáde, ìwọ àti ọ̀dọ́mọkùnrin rẹ Ṣeari-Jaṣubu láti pàdé Ahasi ní ìpẹ̀kun ìṣàn omi ti adágún òkè, ní òpópó ọ̀nà tí ó lọ sí pápá Alágbàfọ̀.