Fò sí àkóónú

Mahershalalhashbaz

2 ẹsẹ · 2 ọmọ ẹbí

A tún mọ̀ ọ́n sí: Maher-shalal-hash-baz

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Mahershalalhashbaz

  1. Olúwa sọ fún mi pé, mú ìwé ńlá kan, kí o sì fi kálàmù ìkọ̀wé lásán kọ Maha-Ṣalali-Haṣi-Basi.

  2. Lẹ́yìn náà, mo lọ sí ọ̀dọ̀ wòlíì obìnrin náà, ó sì lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Olúwa sì wí fún mi pé, “Pe orúkọ rẹ̀ ní Maha-Ṣalali-Haṣi-Basi.