Ram 1 ẹsẹ Wá "Ram" Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Ram Jobu 32:2Nígbà náà ni inú bí Elihu ọmọ Barakeli ará Busi, láti ìbátan ìdílé Ramu; ó bínú si Jobu nítorí ti ó dá ara rẹ̀ láre kàkà ki ó dá Ọlọ́run láre.