Loruhamah 2 ẹsẹ · 4 ọmọ ẹbí A tún mọ̀ ọ́n sí: Lo-ruhamah Wá "Loruhamah" Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Loruhamah Hosea 1:6Gomeri sì tún lóyún, ó sì bí ọmọbìnrin kan. Olúwa sọ fún un pé, “Pe orúkọ rẹ̀ ní Lo-ruhama, nítorí pé, Èmi kò ní ṣàánú fún ilé Israẹli mọ́, Èmi kò sì ní dáríjì wọ́n.Hosea 1:8Lẹ́yìn ìgbà tí ó gba ọmú lẹ́nu Lo-ruhama, ó sì lóyún ó sì bí ọmọkùnrin mìíràn. Nígbà náà ni