Jedaiah
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Jedaiah
Ìpín èkínní jáde sí Jehoiaribu, èkejì sí Jedaiah,
Àwọn àlùfáà. Àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973)
Àwọn àlùfáà: àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973)