Jaddua
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Jaddua
Joiada ni baba Jonatani, Jonatani sì ni baba Jaddua.
Àwọn olórí ìdílé àwọn ọmọ Lefi ní ìgbà ayé Eliaṣibu, Joiada, Johanani àti Jaddua, àti pẹ̀lú ti àwọn àlùfáà ni a kọ sílẹ̀ ní ìgbà ìjọba Dariusi ará Persia.