Heleb
A tún mọ̀ ọ́n sí: Heled, Heldai
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Heleb
Heledi ọmọ Baanah, ará Netofa, Ittai ọmọ Ribai to Gibeah ti àwọn ọmọ Benjamini;
Maharai ará Netofa, Heledi ọmọ Baanah ará Netofa,
Èkejìlá fún oṣù kejìlá jẹ́ Heldai ará Netofa láti ìdílé Otnieli. Ẹgbàá méjìlá (24,000) ọkùnrin ni ó wà ní ìpín tirẹ̀.