Guni
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Guni
Àwọn ọmọ Naftali: Jasieli, Guni, Jeseri, àti Ṣillemu.
Ti àwọn ọmọ Naftali gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Jasieli, ìdílé àwọn ọmọ Jaseeli: ti Guni, ìdílé àwọn ọmọ Guni;
Àwọn ọmọ Naftali: Jasieli, Guni, Jeseri àti Ṣallumu—ọmọ rẹ̀ nípa Biliha.