Demas
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Demas
Luku, arákùnrin wa ọ̀wọ́n, oníṣègùn, àti Dema ki í yín.
Nítorí Dema ti kọ̀ mí sílẹ̀, nítorí ó ń fẹ́ ayé yìí, ó sì lọ sí Tẹsalonika; Kreskeni sí Galatia, Titu sí Dalimatia.
Marku kí ọ pẹ̀lú Aristarku, Dema àti Luku, àwọn alábáṣiṣẹ́ mi.