Anna 1 ẹsẹ · 1 ọmọ ẹbí Wá "Anna" Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Anna Luku 2:36Ẹnìkan sì ń bẹ, Anna wòlíì, ọmọbìnrin Penueli, nínú ẹ̀yà Aṣeri: ọjọ́ ogbó rẹ̀ pọ̀, ó ti bá ọkọ gbé ní ọdún méje láti ìgbà wúńdíá rẹ̀ wá;