Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shelemiah: 1. A porter of the tabernacle
Àwọn ẹsẹ nípa 1. A porter of the tabernacle
Kèké fún ẹnu-ọ̀nà ilà oòrùn bọ́ sí ọ̀dọ̀ Ṣelemiah. Nígbà náà a dá kèké fún ọmọkùnrin rẹ̀ Sekariah, ọlọ́gbọ́n onímọ̀ràn, kèké fún ẹnu-ọ̀nà àríwá sì bọ́ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀.