Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Migdol: 2. A city on the northeastern border of lower Egypt

2 ẹsẹ · 2 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 2. A city on the northeastern border of lower Egypt

  1. Ọ̀rọ̀ Olúwa tọ Jeremiah wá nípa àwọn Júù tí ń gbé ní ìsàlẹ̀ Ejibiti ní Migdoli, Tafanesi àti Memfisi àti ní apá òkè Ejibiti:

  2. “Kéde èyí ní Ejibiti, sì sọ ọ́ ní Migdoli, sọ ọ́ ní Memfisi àti Tafanesi: ‘Dúró sí ààyè rẹ kí o sì múra sílẹ̀, nítorí pé idà náà ń pa àwọn tí ó yí ọ ká.’