Fò sí àkóónú
Saamu 45:16-17

Àsọtẹ́lẹ̀ ogún ọba tí yóò wà títí

Saamu 45:16-17
16
Ọmọ rẹ̀ ni yóò gba ipò baba rẹ̀ ìwọ yóò sì fi wọ́n joyè lórí ilẹ̀ gbogbo.
17
Èmí yóò máa rántí orúkọ rẹ̀ ní ìran gbogbo, nígbà náà ni orílẹ̀-èdè yóò yìn ọ́ láé àti láéláé.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options