Skip to content
Joṣua 18:1-2

A gbé àgọ́ ìpàdé kalẹ̀ ní Ṣílò

Joṣua 18:1-2
1
Gbogbo ìjọ àwọn ọmọ Israẹli péjọ ní Ṣilo, wọ́n si kọ́ àgọ́ ìpàdé ní ibẹ̀. Gbogbo ilẹ̀ náà sì wà ní abẹ́ àkóso wọn,
2
ṣùgbọ́n ó ku ẹ̀yà méje nínú àwọn ọmọ Israẹli tí kò tí ì gba ogún ìní wọn.
Settings

Reading style

Typeface

Font size 19px

Reading width 90 chars

Options