मुख्य मजकुरावर जा
Gẹnẹsisi 49:1-2

Jákọ́bù kó àwọn ọmọ rẹ̀ jọ fún àsọtẹ́lẹ̀

Gẹnẹsisi 49:1-2
1
Nígbà náà ni Jakọbu ránṣẹ́ pe àwọn ọmọ rẹ̀, ó sì wí pé, “Ẹ kó ara yín jọ pọ̀, kí n le è sọ ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ iwájú fún un yín.
2
“Ẹ kó ara yín jọ pọ̀, kí ẹ sì tẹ́tí, ẹ̀yin ọmọ Jakọbu; ẹ fetí sí Israẹli baba yín.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options