Skip to content
Amosi 3:1-2

Ìbáṣepọ̀ Àkànṣe Ísírẹ́ẹ̀lì àti Ìdájọ́ Tí Ń Bọ̀

Amosi 3:1-2
1
Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Olúwa ti sọ nípa rẹ̀, ẹ̀yin ènìyàn Israẹli nípa àwọn ìdílé tí mo mú jáde láti Ejibiti:
2
“Ìwọ nìkan ni ẹni tí mo yàn nínú gbogbo àwọn ìran ayé yìí; nígbà náà èmi ó jẹ ọ́ ní yà fún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.”
Settings

Reading style

Typeface

Font size 19px

Reading width 90 chars

Options