Meshech-Tubal
A tún mọ̀ ọ́n sí: Meshech, Tubal
46.0000, 47.0000 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Meshech-Tubal
“Meṣeki àti Tubali wà níbẹ̀, pẹ̀lú gbogbo ogun wọn yí isà òkú wọn ká. Gbogbo wọn jẹ́ aláìkọlà, wọ́n fi idà pa wọ́n nítorí ẹ̀rù tiwọn tàn ká ilẹ̀ alààyè.