Skip to content

Janoah

1 verse

32.1500, 35.3600 Wo lórí Google Maps

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Janoah

  1. Ní ìgbà Peka ọba Israẹli, Tiglat-Pileseri ọba Asiria wá, ó sì mú Ijoni, Abeli-Beti-Maaka, Janoa, Kedeṣi àti Hasori. Ó gba Gileadi àti Galili pẹ̀lú gbogbo ilẹ̀ Naftali. Ó sì kó àwọn ènìyàn ní ìgbèkùn lọ sí Asiria.