Skip to content

Hadrach

1 verse

33.5100, 36.3100 Wo lórí Google Maps

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Hadrach

  1. Ọ̀rọ̀-ìmọ̀. Ọ̀rọ̀ Olúwa kọjú ìjà sí Hadiraki, Damasku ni yóò sì jẹ́ ibi ìsinmi rẹ̀; nítorí ojú Olúwa ń bẹ lára ènìyàn, àti lára gbogbo ẹ̀yà Israẹli.