Baale-judah
A tún mọ̀ ọ́n sí: Baale
31.7700, 34.9900 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Baale-judah
Dafidi sì dìde, ó sì lọ àti gbogbo àwọn ènìyàn tí ń bẹ́ lọ́dọ̀ rẹ́, láti Baalahi ní Juda wá, láti mú àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run tí ibẹ̀ wá, èyí tí a ń pe orúkọ rẹ̀ ní orúkọ Olúwa àwọn ọmọ-ogun tí ó jókòó láàrín àwọn kérúbù.