Skip to content

Baal-hermon

1 verse

33.4100, 35.8500 Wo lórí Google Maps

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Baal-hermon

  1. Àwọn ìjòyè ìlú Filistini márààrún, gbogbo àwọn ará Kenaani, àwọn ará Sidoni, àti àwọn ará Hifi tí ń gbé ní àwọn òkè Lebanoni bẹ̀rẹ̀ láti òkè Baali-Hermoni títí dé Lebo-Hamati.