Baal-shalishah
A tún mọ̀ ọ́n sí: Baal-shalisha
32.0200, 35.2200 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Baal-shalishah
Ọkùnrin kan wá láti Baali-Ṣaliṣa, ó sì mú àkàrà àkọ́so èso, ogún ìṣù àkàrà barle, tí wọ́n dín láti ara àkọ́so èso àgbàdo, àti pẹ̀lú síírí ọkà tuntun nínú àpò rẹ̀ wá fún ènìyàn Ọlọ́run náà. Òun sì wí pé, “Fún àwọn ènìyàn láti jẹ.”