Fò sí àkóónú
Saamu 24:1-2

Ọlọ́run ni olùní ohun gbogbo tí ó dá

Saamu 24:1-2
1
Ti Dafidi. Saamu. Ti Olúwa ni ilẹ̀, àti ẹ̀kún rẹ̀, ayé àti àwọn tí ó tẹ̀dó sínú rẹ̀;
2
nítorí ó fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lélẹ̀ lórí òkun ó sì gbé e kalẹ̀ lórí àwọn ìṣàn omi.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options