Skip to content
Numeri 2:1-2

Àwọn ìtọ́ni fún gbígbé ibùdó kalẹ̀

Numeri 2:1-2
1
Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni pé,
2
“Kí àwọn ọmọ Israẹli pa àgọ́ wọn yí àgọ́ ìpàdé ká, kí wọ́n jẹ́ kí àgọ́ wọn jìnnà sí i díẹ̀, oníkálùkù lábẹ́ ọ̀págun pẹ̀lú àsíá ìdílé wọn.”
Settings

Reading style

Typeface

Font size 19px

Reading width 90 chars

Options