Skip to content
Lefitiku 11:1-2

Ìṣáájú sí àwọn òfin ohun mímọ́ àti ohun àìmọ́

Lefitiku 11:1-2
1
Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni pé,
2
“Ẹ sọ fún àwọn ara Israẹli pé, ‘Nínú gbogbo ẹranko tí ń gbé lórí ilẹ̀, àwọn wọ̀nyí ni ẹ le jẹ.

Ọ̀rọ̀ Bíbélì: Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™, © 2009, 2017 Biblica, Inc. · CC BY-SA 4.0“Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc., used with permission.